Ẹ Káàbọ̀!

Lítíréṣọ̀ Yorùbá is a bilingual literature website and resource hub focused on Yoruba texts, themes, and writers. À ń pèsè àyíká amáyédẹrùn fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́, olùkọ́, onímọ̀, àti gbogbo olólùfẹ́ lítíréṣọ̀ Yorùbá tí wọ́n fẹ́ kọ́ ẹ̀kọ́, ṣàwárí, tàbí kó ìmọ̀ jọ lórí ìwé Yorùbá, àwọn ònkọ̀wé Yorùbá, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.

Lítíréṣọ̀ Yorùbá is a digital repository of Yoruba literature in its diverse forms.

Our mission is to document and make accessible over 1,000 Yoruba literary works, spanning prose, poetry, drama, children’s books, and oral narratives.

500
Yoruba authors
1,000
Yoruba titles
Fagunwa books

Our scope goes beyond the texts themselves.

A gbàgbọ́ pé lítíréṣọ̀ kì í ṣe ìwé pẹ̀lú ọ̀rọ̀ nìkan. Ìdí nìyí tí a tún fi ń pèsè àkótán ìtàn, ìtúpalẹ̀ ìtàn, àfihàn ẹ̀dá ìtàn, àwọn àkòrí ìtàn, àtẹ̀jáde ìtàn àwọn ònkọ̀wé, àti ìmọ̀ èdè Yorùbá gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe farahàn nínú lítíréṣọ̀.


Yorùbá Literary News

Events, Competitions & Literary Movements

We spotlight literary competitions, author interviews, panel discussions, book launches, and grassroots storytelling projects in the Yorùbá literary space.


Why We Created Lítíréṣọ̀ Yorùbá

Lítíréṣọ̀ Yorùbá was brought to existence to make up for the almost inexistence of Yoruba literature on the webspace. The initiators of this project recognised the need for a novel idea that will project and amplify Yoruba literature for global visibility. It is a project midwifed by several phone calls, social media chats, and meticuluous collaborations of like-minded individuals

Author Spotlights

À ń ṣe àtẹ̀jáde ìtàn àwọn onkọ̀wé Yorùbá àti ipa tí wọ́n ti kó.

Literary Analysis

À ń pèsè ìtúpalẹ̀, àkótán, àfihàn àkóónú, àti ìrànwọ́ àkànṣe fún ìdánwò bí i WAEC, NECO, àti JAMB.

Book Profiles

À ń ṣe àkójọpọ̀ àwọn ìwe lítíréṣọ̀ Yorùbá tó tó ẹgbẹ̀rún kan (1,000).

Koseegbe

Drama

We document key plays, playwrights, premiere dates, plot outlines, and cultural relevance

Yoruba poetry

Poetry

Discover a growing collection of Yoruba poetry.

Ogun Awitele

Prose

Browse a rich catalogue of Yoruba prose works including novels, novellas, and folktale collections.

Latest Additions